Jóṣúà 6:9 BMY

9 Àwọn olùṣọ tí ó hámọ́ra sì lọ níwájú àwọn àlùfáà tí ń fọn fèrè, olùṣọ́ ẹ̀yìn sì tẹ̀-lé àpótí ẹ̀rí náà. Ní gbogbo àsìkò yìí fèrè sì ń dún.

Ka pipe ipin Jóṣúà 6

Wo Jóṣúà 6:9 ni o tọ