Jóṣúà 7:26 BMY

26 Wọ́n sì kó òkítì òkúta ńlá lé Ákánì lórí títí di òní yìí. Nígbà náà ní Olúwa sì yí ìbínú gbígbóná rẹ̀ padà. Nítorí náà ni a ṣe ń pe orúkọ ibẹ̀ ní Àfonífojì Ákórì láti ìgbà náà

Ka pipe ipin Jóṣúà 7

Wo Jóṣúà 7:26 ni o tọ