Jóṣúà 8:1 BMY

1 Nígbà náà ni Olúwa sọ fún Jóṣúà pé, “Má ṣe bẹ̀rù, kí àyà kí ó má ṣe fò ọ́. Kó gbogbo àwọn ọmọ ogun pẹ̀lúù rẹ, kí ẹ gòkè lọ gbógun ti Áì. Nítorí mo ti fi ọba Áì, àwọn ènìyàn an rẹ̀, ìlú u rẹ̀ àti ilẹ̀ ẹ rẹ̀ lé ọ lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Jóṣúà 8

Wo Jóṣúà 8:1 ni o tọ