Jóṣúà 9:15 BMY

15 Nígbà náà ni Jósúà ṣe àdéhùn àlàáfíà pẹ̀lú wọn láti dá wọn sí, àti àwọn olórí ìjọ ènìyàn fi ọwọ́ sí àdéhùn náà nípa ṣíṣe ìbúra.

Ka pipe ipin Jóṣúà 9

Wo Jóṣúà 9:15 ni o tọ