Jóṣúà 9:16 BMY

16 Ní ẹ̀yìn ọjọ́ mẹ́ta tí wọ́n ti ṣe àdéhùn pẹ̀lú àwọn ará Gíbíónì, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gbọ́ pé aládùúgbò wọn ni wọ́n, tí ń gbé ní tòsí wọn.

Ka pipe ipin Jóṣúà 9

Wo Jóṣúà 9:16 ni o tọ