Jóṣúà 9:24 BMY

24 Wọ́n sì dá Jóṣúà lóhùn pé, “Nítorí tí a sọ fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ dájú ṣáká bí Olúwa Ọlọ́run rẹ ti pàṣẹ fún Mósè ìránṣẹ́ rẹ̀, láti fún yín ní gbogbo ilẹ̀ náà, kí ó sì pa gbogbo olùgbé ilẹ̀ náà run kúrò ní iwájú yín. Nítorí náà, àwa bẹ̀rù ẹ̀mí wa nítorí yín, èyí sì ni ìdí tí a fi ṣe bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Jóṣúà 9

Wo Jóṣúà 9:24 ni o tọ