Jóṣúà 9:25 BMY

25 Nísinsinyí, àwa wà ní ọwọ́ yín. Ohunkóhun tí ẹ bá rò pé ó yẹ ó si tọ́ lójú yín ní kí ẹ fi wá ṣe.”

Ka pipe ipin Jóṣúà 9

Wo Jóṣúà 9:25 ni o tọ