Jóṣúà 9:26 BMY

26 Bẹ́ẹ̀ ní Jóṣúà sì gbà wọ́n là kúrò ní ọwọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. Wọn kò sì pa wọ́n.

Ka pipe ipin Jóṣúà 9

Wo Jóṣúà 9:26 ni o tọ