Nehemáyà 1:4 BMY

4 Nígbà tí mo gbọ́ àwọn nǹkan wọ̀nyí, mo jókòó mo sì ṣunkún. Mo ṣọ̀fọ̀, mo gbààwẹ̀, mo sì gbàdúrà fún ọjọ́ díẹ̀ níwájú Ọlọ́run ọ̀run.

Ka pipe ipin Nehemáyà 1

Wo Nehemáyà 1:4 ni o tọ