Nehemáyà 10:37 BMY

37 “Síwájú sí i, àwa yóò mú àkọ́so oúnjẹ ilẹ̀ wa ti ọrẹ oúnjẹ (ọkà), ti gbogbo èṣo àwọn igi àti ti wáìnì túntún wa àti ti òróró wá sí yàrá ìpamọ́ ilé Ọlọ́run wa àti fún àwọn àlùfáà. Àwa yóò sì mú ìdámẹ́wàá ohun ọ̀gbìn wá fún àwọn ọmọ Léfì, nítorí àwọn ọmọ Léfì ni ó ń gba ìdáwẹ́wàá ní gbogbo àwọn ìlú tí a ti ń ṣiṣẹ́.

Ka pipe ipin Nehemáyà 10

Wo Nehemáyà 10:37 ni o tọ