Nehemáyà 10:38 BMY

38 Àlùfáà tí o ti ìdílé Árónì wá ni yóò wá pẹ̀lú àwọn ọmọ Léfì nígbà tí wọ́n bá ń gba ìdámẹ́wàá, àwọn ọmọ Léfì yóò sì mú ìdámẹ́wàá ti ìdámẹ́wàá náà wá sí ilé Ọlọ́run, sí yàrá ìpamọ́ inú ilé ìṣúra.

Ka pipe ipin Nehemáyà 10

Wo Nehemáyà 10:38 ni o tọ