Nehemáyà 10:39 BMY

39 Àwọn ènìyàn Ísírẹ́lì, àti àwọn ọmọ Léfì gbọdọ̀ mú ọrẹ oúnjẹ (ọkà), wáìnì túntún àti òróró wá sí yàrá ìpamọ́ níbi tí a pa ohun èlò ibi mímọ́ mọ́ sí àti ibi tí àwọn àlùfáà-tí-ń ṣe-ìránṣẹ́-lọ́wọ́, àwọn aṣọ́nà àti àwọn akọrin máa rí dúró sí.“Àwa kì yóò gbàgbé tàbí ṣe àìbìkítà nípa ilé Ọlọ́run wa.”

Ka pipe ipin Nehemáyà 10

Wo Nehemáyà 10:39 ni o tọ