Nehemáyà 12:12 BMY

12 Ní ìgbé ayé Jòíakímù, wọ̀nyí ni àwọn olórí àwọn ìdílé àwọn àlùfáà:ti ìdílé Ṣeráiáyà, Méráyà;ti ìdílé Jeremáyà, Hananíyà;

Ka pipe ipin Nehemáyà 12

Wo Nehemáyà 12:12 ni o tọ