Nehemáyà 12:38 BMY

38 Àwọn ẹgbẹ́ akọrin kejì gba ọ̀nà òdì kejì lọ. Mo tẹ̀lé wọn ní orí odi, pẹ̀lú ìdajì àwọn ènìyàn, kọjá ilé ìṣọ́ ìléru lọ sí odi fífẹ̀,

Ka pipe ipin Nehemáyà 12

Wo Nehemáyà 12:38 ni o tọ