Nehemáyà 13:3 BMY

3 Nígbà tí àwọn ènìyàn gbọ́ òfin yìí, wọ́n yọ gbogbo àwọn àjòjì ènìyàn tí ó dara pọ̀ mọ́ wọn kúrò láàrin àwọn Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Nehemáyà 13

Wo Nehemáyà 13:3 ni o tọ