Nehemáyà 2:10 BMY

10 Nígbà tí Ṣáńbálátì ará Hórónì àti Tòbáyà ará a Ámónì tí wọ́n jẹ́ ìjòyè gbọ́ nípa èyí pé, ẹnikan wá láti mú ìtẹ̀ṣíwájú bá àlàáfíà àwọn ará Ísírẹ́lì inú bí wọn gidigidi.

Ka pipe ipin Nehemáyà 2

Wo Nehemáyà 2:10 ni o tọ