Nehemáyà 2:9 BMY

9 Bẹ́ẹ̀ ni mo lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn baálẹ̀ Agèégbè Yúfúrátè mo sì fún wọn ní àwọn lẹ́tà ọba. Ọba sì ti rán àwọn ológun àti àwọn ẹlẹ́ṣin ogun pẹ̀lúu mi.

Ka pipe ipin Nehemáyà 2

Wo Nehemáyà 2:9 ni o tọ