Nehemáyà 2:13 BMY

13 Ní òru, mo jáde lọ sí àfonífojì ibodè sí ìhà kànga Jákálì àti sí ẹnu ibodè jààtàn àti ẹnu ibodè rẹ̀ èyí tí ó ti wó lulẹ̀, tí a ti fi iná sun.

Ka pipe ipin Nehemáyà 2

Wo Nehemáyà 2:13 ni o tọ