Nehemáyà 2:14 BMY

14 Nígbà náà ni mo lọ sí ẹnu ibodè oríṣun àti sí adágún omi ọba, ṣùgbọ́n kò sí ààyè tó fún ẹranko mi láti kọjá;

Ka pipe ipin Nehemáyà 2

Wo Nehemáyà 2:14 ni o tọ