Nehemáyà 2:3 BMY

3 Ṣùgbọ́n mo wí fún ọba pé, “Kí ọba kí ó pẹ́! È é ṣe tí ojú mi ko ṣe ní fàro, nígbà tí ìlú tí a sin àwọn baba mi sí wà ní ahoro, tí a sì ti fi iná run àwọn ibodè rẹ̀?”

Ka pipe ipin Nehemáyà 2

Wo Nehemáyà 2:3 ni o tọ