20 Lẹ́yìn rẹ̀ ni Bárúkù ọmọ Ṣábáyì fi ìtaa tún apá mìíràn ṣe, láti orígun dé ẹnu ọ̀nà ilé Élíáṣíbù olórí àlùfáà.
Ka pipe ipin Nehemáyà 3
Wo Nehemáyà 3:20 ni o tọ