Nehemáyà 3:21 BMY

21 Lẹ́yìn rẹ̀ ni, Mérémótì ọmọ Úráyà, ọmọ Hákósì tún apá mìíràn ṣe, láti ẹnu ọ̀nà ilé Élíáṣíbù títí dé òpin rẹ̀

Ka pipe ipin Nehemáyà 3

Wo Nehemáyà 3:21 ni o tọ