Nehemáyà 3:29 BMY

29 Lẹ́yìn wọn, Ṣádókì ọmọ Ímérì tún ọ̀kánkán ilé rẹ̀ ṣe. Lẹ́yìn rẹ̀ ni Ṣémáyà ọmọ Ṣekanáyà, olùṣọ́ ibodè ìhà ìlà oòrùn ṣe àtúnṣe.

Ka pipe ipin Nehemáyà 3

Wo Nehemáyà 3:29 ni o tọ