Nehemáyà 7:4 BMY

4 Ìlú náà tóbi ó sì ní ààyè, ṣùgbọ́n ènìyàn inú rẹ̀ kéré, a kò sì tí ì tún àwọn ilé inú rẹ̀ kọ́.

Ka pipe ipin Nehemáyà 7

Wo Nehemáyà 7:4 ni o tọ