Nehemáyà 9:1 BMY

1 Ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kan náà, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì péjọ pọ̀, wọ́n gbààwẹ̀, wọ́n wọ aṣọ ọ̀fọ̀, wọ́n sì da eruku sórí ara wọn.

Ka pipe ipin Nehemáyà 9

Wo Nehemáyà 9:1 ni o tọ