Nehemáyà 9:2 BMY

2 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì ya ara wọn ṣọ́tọ̀ kúrò nínú un gbogbo àwọn àlejò. Wọ́n dúró ní ààyè e wọn, wọ́n sì ń jẹ́wọ́ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ẹ wọn àti iṣẹ́ búburú àwọn baba wọn.

Ka pipe ipin Nehemáyà 9

Wo Nehemáyà 9:2 ni o tọ