Nehemáyà 9:10 BMY

10 Ìwọ rán iṣẹ́ àmì àti isẹ́ ìyanu sí Fáráò, sí gbogbo àwọn ìjòyèe rẹ̀ àti sí gbogbo ènìyàn ilẹ̀ ẹ rẹ̀, nítorí ìwọ mọ ìwà ìgbéraga tí àwọn ará Éjíbítì hù sí wọn. Ìwọ ra orúkọ fún araà rẹ, èyí tí ó sì wà títí di òní yìí.

Ka pipe ipin Nehemáyà 9

Wo Nehemáyà 9:10 ni o tọ