Nehemáyà 9:11 BMY

11 Ìwọ pín òkun níwájúu wọn, nítorí kí wọn lè kọjá ní ìyàngbẹ ilẹ̀, ṣùgbọ́n ìwọ sọ àwọn tí ń lépa wọn sínú ibú, bí òkúta sínú omi ńlá.

Ka pipe ipin Nehemáyà 9

Wo Nehemáyà 9:11 ni o tọ