Nehemáyà 9:12 BMY

12 Ní ọ̀sán ìwọ daríi wọn pẹ̀lú òpó ìkúùkú àti ní òru ni ìwọ daríi wọn pẹ̀lú òpó iná láti fún wọn ní ìmọ́lẹ̀ ní ọ̀nà tí wọn yóò gbà.

Ka pipe ipin Nehemáyà 9

Wo Nehemáyà 9:12 ni o tọ