Nehemáyà 9:13 BMY

13 “Ìwọ sọ̀kalẹ̀ wá sí orí òkè Ṣínáì; ìwọ bá wọn sọ̀rọ̀ láti ọ̀run. Ìwọ fún wọn ní ìlànà àti àwọn òfin tí ó jẹ́ òdodo tí ó sì tọ́ àti ìlànà tí ó dára.

Ka pipe ipin Nehemáyà 9

Wo Nehemáyà 9:13 ni o tọ