Nehemáyà 9:25 BMY

25 Wọ́n gba àwọn ìlú olódì àti ilẹ̀ ọlọ́ràá; wọ́n gba àwọn ilé tí ó kún fún onírúurú gbogbo nǹkan rere, àwọn kàǹga tí a ti gbẹ́, awọn ọgbà àjàrà, awọn ọgbà ólífì àti àwọn igi eléso ní ọ̀pọ̀lọpọ̀. Wọ́n jẹ, wọ́n yó, wọ́n sì sanra dáadáa; wọ́n sì yọ̀ nínú oore ńlá rẹ

Ka pipe ipin Nehemáyà 9

Wo Nehemáyà 9:25 ni o tọ