Nehemáyà 9:26 BMY

26 “Ṣùgbọ́n wọ́n ṣe àìgbọ́ràn, wọ́n sì ṣọ̀tẹ̀ sí ọ; wọ́n gbàgbé òfin rẹ. Wọ́n pa àwọn wòlíì rẹ, tí o fi gbà wọn ni ìyànjú pé kí wọn yí padà sí ọ; wọ́n sì ṣe ọ̀rọ̀-òdì tí ó burú jàì.

Ka pipe ipin Nehemáyà 9

Wo Nehemáyà 9:26 ni o tọ