Nehemáyà 9:27 BMY

27 Nítorí náà, ìwọ fi wọ́n lé àwọn ọ̀taa wọn lọ́wọ́, àwọn tí ó ni wọ́n lára. Ṣùgbọ́n nígbà tí a ni wọ́n lára wọ́n kígbe sí ọ. Ìwọ gbọ́ wọn láti ọ̀run wá àti nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àánú rẹ, ìwọ fún wọn ní olùgbàlà, tí ó gbà wọ́n lọ́wọ́ àwọn ọ̀ta wọn.

Ka pipe ipin Nehemáyà 9

Wo Nehemáyà 9:27 ni o tọ