Nehemáyà 9:28 BMY

28 “Ṣùgbọ́n bí wọ́n bá ti wà nínú ìsinmi, wọn a sì tún ṣe búburú lójùu rẹ. Nígbà náà ni ìwọ kọ̀ wọ́n sílẹ̀ sọ́wọ́ àwọn ọ̀ta kí wọ́n lè jọba lóríi wọn. Nígbà tí wọ́n bá sì tún kígbe sí ọ, ìwọ a gbọ́ láti ọ̀run wá, àti nínú àánú rẹ ni ìwọ gbà láti ìgbà dé ìgbà.

Ka pipe ipin Nehemáyà 9

Wo Nehemáyà 9:28 ni o tọ