Nehemáyà 9:29 BMY

29 “Ìwọ kìlọ̀ fún wọn làti Padà sínú òfin rẹ, ṣùgbọ́n wọ́n hu ìwà ìgbéraga, wọ́n sì ṣe àìgbọ́ràn si àṣẹ rẹ. Wọ́n sẹ̀ sí ìlànà rẹ, nípa èyí tí ènìyàn yóò yè tí wọ́n bá pa wọ́n mọ́. Nínú agídí ọkàn wọ́n kọ ẹ̀yìn sí ọ, wọ́n jẹ́ olóríkunkun wọn kò sì fẹ́ gbọ́.

Ka pipe ipin Nehemáyà 9

Wo Nehemáyà 9:29 ni o tọ