Nehemáyà 9:30 BMY

30 Fún ọ̀pọ̀lọ̀pọ̀ ọdún ni ìwọ fi ní ṣùúrù pẹ̀lùu wọn. Nìpa ẹ̀míì rẹ ni ìwọ kìlọ̀ fún wọn nípaṣẹ̀ àwọn wòlíì. Síbẹ̀ wọn kò fi etí sílẹ̀, nìtorì náà ni ìwọ ṣe fi wọ́n lé àwọn aládùúgbò wọn lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Nehemáyà 9

Wo Nehemáyà 9:30 ni o tọ