Nehemáyà 9:31 BMY

31 Ṣùgbọ́n nínú ọ̀pọ̀ àánú rẹ, ìwọ kò mú òpin bá wọn tàbí kọ̀ wọ́n sílẹ̀, nítorí ìwọ ni Ọlọ́run olóore ọ̀fẹ́ àti aláàánú.

Ka pipe ipin Nehemáyà 9

Wo Nehemáyà 9:31 ni o tọ