Nehemáyà 9:6 BMY

6 Ìwọ nìkan ni Olúwa. Ìwọ ni ó dá àwọn ọ̀run, àní àwọn ọ̀run tí ó ga jù àti àìlónkà ogun ọ̀run wọn, ayé àti gbogbo ohun tó wà nínú un rẹ̀, àwọn òkun àti gbogbo ohun tó wà nínú un wọn. Ìwọ fún gbogbo wọn ní ìyè àìlónkà àwọn ogun ọ̀run sì ń sìn ọ́.

Ka pipe ipin Nehemáyà 9

Wo Nehemáyà 9:6 ni o tọ