Nehemáyà 9:7 BMY

7 “Ìwọ ni Olúwa Ọlọ́run, tí ó yan Ábúrámù tí ó sì mú u jáde láti Úrì ti Kálídéà, tí ó sì sọ orúkọ rẹ̀ ní Ábúráhámù.

Ka pipe ipin Nehemáyà 9

Wo Nehemáyà 9:7 ni o tọ