1 Kọ́ríńtì 1:7 BMY

7 Nítorí náà ẹ̀yin kò ṣe aláìní nínú èyíkéyì ẹ̀bùn ẹ̀mí, bí ẹ̀yin ṣe ń retí ìfarahàn Olúwa wa Jésù Kírísítì.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 1

Wo 1 Kọ́ríńtì 1:7 ni o tọ