1 Kọ́ríńtì 10:28 BMY

28 Bí ẹnikẹ́nì bá sì kìlọ̀ fún un yín pé a ti fi ẹran yìí rúbọ sí òriṣà, má ṣe jẹ́ ẹ nítorí ẹ̀rí ọkàn tí ó kìlọ̀ fún ọ́ pé a ti fi rúbọ sí òrìṣà.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 10

Wo 1 Kọ́ríńtì 10:28 ni o tọ