1 Kọ́ríńtì 13:2 BMY

2 Bí mo bá ní ẹ̀bùn ìsọtẹ́lẹ́, tí mo sì ní òye gbogbo ohun ìjìnlẹ̀, àti gbogbo ìmọ̀, bí mo sì ni gbogbo ìgbàgbọ́ tó bẹ́ẹ̀ tí mo lè sí àwọn òkè ńlá nídìí, tí èmi kò sì ní ìfẹ́, èmi kò jẹ nǹkan kan.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 13

Wo 1 Kọ́ríńtì 13:2 ni o tọ