1 Kọ́ríńtì 13:3 BMY

3 Bí mo bá fi gbogbo nǹkan tí mo ní tọrẹ fún àwọn aláìní, tí mo sì fi ara mi fún ni láti sùn ṣùgbọ́n tí n kò ní ìfẹ̀, kò ní èrè kan fún mi.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 13

Wo 1 Kọ́ríńtì 13:3 ni o tọ