1 Kọ́ríńtì 13:4 BMY

4 Ìfẹ́ a máa mú sùúrù, ìfẹ́ a máa ṣeun, ìfẹ̀ kì í ṣe ìlara, ìfẹ́ kì í fẹ̀, ìfẹ́ kì í sọ̀rọ̀ ìgbéraga.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 13

Wo 1 Kọ́ríńtì 13:4 ni o tọ