1 Kọ́ríńtì 5:9 BMY

9 Nígbà tí mo kọ̀wé ṣáájú sí i yín, mo sọ fún yín pé, kí ẹ má ṣe darapọ̀ pẹ̀lú àwọn alágbérè ènìyàn.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 5

Wo 1 Kọ́ríńtì 5:9 ni o tọ