Máàkù 1:13 BMY

13 Ó sì wà níbẹ̀ fún ogójì ọjọ́. A sì fi Í lé Èṣù lọ́wọ́ láti dán an wò. Àwọn ańgẹ́lì sì wá ṣe ìtọ́jú Rẹ̀.

Ka pipe ipin Máàkù 1

Wo Máàkù 1:13 ni o tọ