Máàkù 1:16 BMY

16 Ní ọjọ́ kan, bí Jésù ti ń rìn létí òkun Gálílì, Ó rí Ṣímónì àti Ańdérù arákùnrin rẹ̀, wọ́n ń fi àwọ̀n wọn pẹja torí pé Apẹja ni wọ́n.

Ka pipe ipin Máàkù 1

Wo Máàkù 1:16 ni o tọ