Máàkù 1:19 BMY

19 Bí Ó sì ti rìn ṣíwájú díẹ̀, ní etí òkun, Ó rí Jákọ́bù àti Jòhánù, àwọn ọmọ Sébédè nínú ọkọ̀ wọ́n ń tún àwọ̀n wọn ṣe.

Ka pipe ipin Máàkù 1

Wo Máàkù 1:19 ni o tọ