Máàkù 1:21 BMY

21 Lẹ́yìn náà, Jésù àti àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ wọ ìlú Kapanámù, nígbà tí ó di òwúrọ̀ ọjọ́ ìsimi, ó lọ sínú sínágọ́gù, ó sì ń kọ́ni.

Ka pipe ipin Máàkù 1

Wo Máàkù 1:21 ni o tọ