Máàkù 10:42 BMY

42 Nítorí ìdí èyí, Jésù pè wọ́n sọ́dọ̀, ó sì wí fún wọn pé, “Gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yin ti mọ̀ pé, àwọn ọba àti àwọn kèfèrí ń lo agbára lórí àwọn ènìyàn.

Ka pipe ipin Máàkù 10

Wo Máàkù 10:42 ni o tọ